O. Daf 83:5-7 Yorùbá Bibeli (YCE)

5. Nitoriti nwọn ti gbimọ̀ pọ̀ ṣọkan: nwọn ti dimọlu si ọ.

6. Agọ Edomu, ati ti awọn ọmọ Iṣmaeli; ti Moabu, ati awọn ọmọ Hagari.

7. Gebali, ati Ammoni, ati Amaleki: awọn ara Filistia pẹlu awọn ara Tire;

O. Daf 83