O. Daf 80:16-18 Yorùbá Bibeli (YCE)

16. O jona, a ke e lulẹ: nwọn ṣegbe nipa ibawi oju rẹ.

17. Jẹ ki ọwọ rẹ ki o wà lara ọkunrin ọwọ ọtún rẹ nì, lara ọmọ-enia ti iwọ ti mule fun ara rẹ.

18. Bẹ̃li awa kì yio pada sẹhin kuro lọdọ rẹ: mu wa yè, awa o si ma pè orukọ rẹ.

O. Daf 80