O. Daf 80:13-15 Yorùbá Bibeli (YCE)

13. Imado lati inu igbo wá mba a jẹ, ati ẹranko igbẹ njẹ ẹ run.

14. Yipada, awa mbẹ ọ, Ọlọrun awọn ọmọ-ogun: wolẹ lati ọrun wá, ki o si wò o, ki o si bẹ àjara yi wò:

15. Ati agbala-àjara ti ọwọ ọtún rẹ ti gbin, ati ọmọ ti iwọ ti mule fun ara rẹ.

O. Daf 80