O. Daf 8:7-9 Yorùbá Bibeli (YCE)

7. Awọn agutan ati awọn malu pẹlu, ati awọn ẹranko igbẹ;

8. Awọn ẹiyẹ oju ọrun, ati awọn ẹja okun, ti o nkọja lọ nipa ọ̀na okun.

9. Oluwa, Oluwa wa, orukọ rẹ ti ni iyìn to ni gbogbo aiye!

O. Daf 8