O. Daf 79:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori kili awọn keferi yio ṣe wipe, Nibo li Ọlọrun wọn wà? jẹ ki a mọ̀ igbẹsan ẹ̀jẹ awọn iranṣẹ rẹ ti a ta silẹ loju wa ninu awọn keferi.

O. Daf 79

O. Daf 79:8-13