O. Daf 78:62-64 Yorùbá Bibeli (YCE)

62. O fi awọn enia rẹ̀ fun idà pẹlu; o si binu si ilẹ-ini rẹ̀.

63. Iná run awọn ọdọmọkunrin wọn; a kò si fi orin sin awọn wundia wọn ni iyawo.

64. Awọn alufa wọn ti oju idà ṣubu; awọn opó wọn kò si pohunrere ẹkún.

O. Daf 78