O. Daf 78:32-35 Yorùbá Bibeli (YCE)

32. Ninu gbogbo wọnyi nwọn nṣẹ̀ siwaju, nwọn kò si gbà iṣẹ iyanu rẹ̀ gbọ́.

33. Nitorina li o ṣe run ọjọ wọn li asan, ati ọdun wọn ni ijaiya.

34. Nigbati o pa wọn, nigbana ni nwọn wá a kiri: nwọn si pada, nwọn bère Ọlọrun lakokò,

35. Nwọn si ranti pe, Ọlọrun li apata wọn, ati Ọlọrun Ọga-ogo li Oludande wọn,

O. Daf 78