O. Daf 72:19-20 Yorùbá Bibeli (YCE) Olubukún li orukọ rẹ̀ ti o li ogo titi lai: ki gbogbo aiye ki o si kún fun ogo rẹ̀; Amin Amin. Adura Dafidi