O. Daf 69:36 Yorùbá Bibeli (YCE)

Iru-ọmọ awọn iranṣẹ rẹ̀ pẹlu ni yio ma jogun rẹ̀: awọn ti o si fẹ orukọ rẹ̀ ni yio ma gbe inu rẹ̀.

O. Daf 69

O. Daf 69:30-36