O. Daf 6:1 Yorùbá Bibeli (YCE)

OLUWA, máṣe ba mi wi ni ibinu rẹ, ki iwọ ki o má ṣe nà mi ni gbigbona ibinujẹ rẹ.

O. Daf 6

O. Daf 6:1-6