O. Daf 58:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Lati inu iya wọn wá li awọn enia buburu ti ṣe iyapa: nwọn ti ṣina lojukanna ti a ti bi wọn, nwọn a ma ṣeke.

O. Daf 58

O. Daf 58:1-8