O. Daf 55:3-5 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Nitori ohùn ọta nì, nitori inilara enia buburu: nitoriti nwọn mu ibi ba mi, ati ni ibinu, nwọn dẹkun fun mi.

4. Aiya dùn mi gidigidi ninu mi: ipaiya ikú si ṣubu lù mi.

5. Ibẹ̀ru ati ìwárìrì wá si ara mi, ati ibẹ̀ru ikú bò mi mọlẹ.

O. Daf 55