O. Daf 5:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ohùn mi ni iwọ o gbọ́ li owurọ, Oluwa, li owurọ li emi o gbà adura mi si ọ, emi o si ma wòke.

O. Daf 5

O. Daf 5:1-9