O. Daf 48:12-14 Yorùbá Bibeli (YCE)

12. Rìn Sioni kiri, ki o si yi i ka: kà ile-iṣọ rẹ̀.

13. Kiyesi odi rẹ̀, kiyesi ãfin rẹ̀ wọnni; ki ẹnyin le ma wi fun iran atẹle nyin.

14. Nitori Ọlọrun yi Ọlọrun wa ni lai ati lailai: on ni yio ma ṣe amọna wa titi ikú.

O. Daf 48