O. Daf 45:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọbinrin awọn alade wà ninu awọn ayanfẹ rẹ: li ọwọ ọtún rẹ li ayaba na gbe duro ninu wura Ofiri.

O. Daf 45

O. Daf 45:1-12