O. Daf 44:25-26 Yorùbá Bibeli (YCE) Nitoriti a tẹri ọkàn wa ba sinu ekuru: inu wa dì mọ erupẹ ilẹ. Dide fun iranlọwọ wa, ki o si rà wa pada