O. Daf 40:14 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki oju ki o tì wọn, ki nwọn ki o si damu pọ̀, awọn ti nwá ọkàn mi lati pa a run; ki a lé wọn pada sẹhin, ki a si dojuti awọn ti nfẹ mi ni ibi.

O. Daf 40

O. Daf 40:7-17