O. Daf 35:15 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn ninu ipọnju mi nwọn yọ̀, nwọn si kó ara wọn jọ: awọn enia-kenia kó ara wọn jọ si mi, emi kò si mọ̀; nwọn fa mi ya, nwọn kò si dakẹ.

O. Daf 35

O. Daf 35:10-18