O. Daf 31:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitori iwọ li apata mi ati odi mi: nitorina nitori orukọ rẹ ma ṣe itọ́ mi, ki o si ma ṣe amọ̀na mi.

O. Daf 31

O. Daf 31:1-11