O. Daf 3:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Dide Oluwa; gbà mi, Ọlọrun mi: nitori iwọ li o lù gbogbo awọn ọta mi li egungun ẹrẹkẹ; iwọ si ká ehin awọn enia buburu.

O. Daf 3

O. Daf 3:3-8