O. Daf 29:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE) Ẹ FI fun Oluwa, ẹnyin ọmọ awọn alagbara, ẹ fi ogo ati agbara fun Oluwa. Ẹ fi ogo fun Oluwa, ti o yẹ fun