O. Daf 28:8-9 Yorùbá Bibeli (YCE) Oluwa li agbara wọn, on si li agbara igbala ẹni-ororo rẹ̀. Gbà awọn enia rẹ là, ki o si busi ilẹ-ini rẹ