O. Daf 26:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. ṢE idajọ mi, Oluwa; nitori ti mo ti nrìn ninu ìwa titọ mi; emi ti gbẹkẹle Oluwa pẹlu; njẹ ẹsẹ mi kì yio yẹ̀.

2. Wadi mi, Oluwa, ki o si ridi mi; dán inu mi ati ọkàn mi wò.

3. Nitoriti iṣeun-ifẹ rẹ mbẹ niwaju mi: emi si ti nrìn ninu otitọ rẹ.

O. Daf 26