O. Daf 2:4-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

4. Ẹniti o joko li ọrun yio rẹrin: Oluwa yio yọ ṣùti si wọn.

5. Nigbana ni yio sọ̀rọ si wọn ni ibinu rẹ̀, yio si yọ wọn lẹnu ninu ibinujẹ rẹ̀ kikan.

6. Ṣugbọn mo ti fi Ọba mi jẹ lori Sioni, òke mimọ́ mi.

O. Daf 2