O. Daf 145:19 Yorùbá Bibeli (YCE)

Yio mu ifẹ awọn ti mbẹ̀ru rẹ̀ ṣẹ: yio gbọ́ igbe wọn pẹlu, yio si gbà wọn.

O. Daf 145

O. Daf 145:14-21