O. Daf 139:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. OLUWA, iwọ ti wadi mi, iwọ si ti mọ̀ mi.

2. Iwọ mọ̀ ijoko mi ati idide mi, iwọ mọ̀ iro mi li ọ̀na jijin rére.

3. Iwọ yi ipa ọ̀na mi ká ati ibulẹ mi, gbogbo ọ̀na mi si di mimọ̀ fun ọ.

O. Daf 139