O. Daf 129:3-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Awọn awalẹ̀ walẹ si ẹhin mi: nwọn si la aporo wọn gigun.

4. Olododo li Oluwa: o ti ke okùn awọn enia buburu kuro.

5. Ki gbogbo awọn ti o korira Sioni ki o dãmu, ki nwọn ki o si yi ẹhin pada.

6. Ki nwọn ki o dabi koriko ori-ile ti o gbẹ danu, ki o to dagba soke:

O. Daf 129