O. Daf 128:3 Yorùbá Bibeli (YCE)

Obinrin rẹ yio dabi àjara rere eleso pupọ li arin ile rẹ: awọn ọmọ rẹ yio dabi igi olifi yi tabili rẹ ka.

O. Daf 128

O. Daf 128:1-6