O. Daf 126:3-6 Yorùbá Bibeli (YCE)

3. Oluwa ṣe ohun nla fun wa: nitorina awa nyọ̀.

4. Oluwa mu ikólọ wa pada, bi iṣan-omi ni gusu.

5. Awọn ti nfi omije fún irugbin yio fi ayọ ka.

6. Ẹniti nfi ẹkun rìn lọ, ti o si gbé irugbin lọwọ, lõtọ, yio fi ayọ̀ pada wá, yio si rù iti rẹ̀.

O. Daf 126