O. Daf 121:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. EMI o gbé oju mi si ori oke wọnnì, nibo ni iranlọwọ mi yio ti nwa?

2. Iranlọwọ mi yio ti ọwọ Oluwa wá, ti o da ọrun on aiye.

3. On kì yio jẹ́ ki ẹsẹ rẹ ki o yẹ̀; ẹniti npa ọ mọ́ kì yio tõgbe.

O. Daf 121