O. Daf 119:1-3 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. IBUKÚN ni fun awọn ẹniti o pé li ọ̀na na, ti nrìn ninu ofin Oluwa.

2. Ibukún ni fun awọn ti npa ẹri rẹ̀ mọ́, ti si nwá a kiri tinu-tinu gbogbo.

3. Nwọn kò dẹṣẹ pẹlu: nwọn nrìn li ọ̀na rẹ̀.

O. Daf 119