O. Daf 113:1-2 Yorùbá Bibeli (YCE)

1. Ẹ ma yìn Oluwa! Ẹ ma yìn, ẹnyin iranṣẹ Oluwa, ẹ ma yìn orukọ Oluwa.

2. Ibukún li orukọ Oluwa lati isisiyi lọ ati si i lailai.

O. Daf 113