O. Daf 10:7 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ẹnu rẹ̀ kún fun egún, ati fun ẹ̀tan, ati fun itanjẹ: ìwa-ìka ati ìwa-asan mbẹ labẹ ahọn rẹ̀.

O. Daf 10

O. Daf 10:1-13