O. Daf 1:5 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nitorina awọn enia buburu kì yio dide duro ni idajọ, bẹ̃li awọn ẹlẹṣẹ kì yio le duro li awujọ awọn olododo.

O. Daf 1

O. Daf 1:1-6