Num 7:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn kò fi fun awọn ọmọ Kohati: nitoripe iṣẹ-ìsin ibi-mimọ́ ni ti wọn; li ohun ti nwọn o ma fi ejika rù.

Num 7

Num 7:5-18