Num 6:16 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki alufa ki o mú wọn wá siwaju OLUWA, ki o si ru ẹbọ ẹ̀ṣẹ rẹ̀ ati ẹbọ sisun rẹ̀:

Num 6

Num 6:10-18