Num 5:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ati gbogbo ẹbọ agbesọsoke ohun mimọ́ gbogbo ti awọn ọmọ Israeli, ti nwọn mú tọ̀ alufa wá, yio jẹ́ tirẹ̀.

Num 5

Num 5:1-13