Num 5:25 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nigbana li alufa yio gbà ẹbọ ohunjijẹ owú na li ọwọ́ obinrin na, yio si fì ẹbọ ohunjijẹ na niwaju OLUWA, yio si ru u lori pẹpẹ:

Num 5

Num 5:21-26