Num 4:8 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki nwọn ki o si nà aṣọ ododó bò wọn, ki nwọn ki o si fi awọ seali bò o, ki nwọn ki o si tẹ̀ ọpá rẹ̀ bọ̀ ọ.

Num 4

Num 4:1-16