Num 4:46 Yorùbá Bibeli (YCE)

Gbogbo awọn ti a kà ninu awọn ọmọ Lefi, ti Mose ati Aaroni ati awọn olori Israeli kà, nipa idile wọn, ati gẹgẹ bi ile baba wọn,

Num 4

Num 4:43-49