Num 33:4 Yorùbá Bibeli (YCE)

Bi awọn ara Egipti ti nsinkú gbogbo awọn akọ́bi wọn ti OLUWA kọlù ninu wọn: lara awọn oriṣa wọn pẹlu li OLUWA ṣe idajọ.

Num 33

Num 33:1-5