Num 33:26-30 Yorùbá Bibeli (YCE)

26. Nwọn si ṣí kuro ni Makhelotu, nwọn si dó si Tahati.

27. Nwọn si ṣí kuro ni Tahati, nwọn si dó si Tera.

28. Nwọn si ṣí kuro ni Tera, nwọn si dó si Mitka.

29. Nwọn si ṣí kuro ni Mitka, nwọn si dó si Haṣmona.

30. Nwọn si ṣí kuro ni Haṣmona, nwọn si dó si Moserotu.

Num 33