Num 32:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Awọn ọmọ Makiri ọmọ Manase si lọ si Gileadi, nwọn si gbà a, nwọn si lé awọn ọmọ Amori ti o wà ninu rẹ̀.

Num 32

Num 32:33-42