Num 32:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ṣugbọn awọn iranṣẹ rẹ yio gòke odò, olukuluku ni ihamọra ogun, niwaju OLUWA lati jà, bi oluwa mi ti wi.

Num 32

Num 32:25-29