Num 31:49 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si wi fun Mose pe, Awọn iranṣẹ rẹ ti kà iye awọn ologun, ti mbẹ ni itọju wa, ọkunrin kan ninu wa kò si din.

Num 31

Num 31:39-54