Num 31:39 Yorùbá Bibeli (YCE)

Kẹtẹkẹtẹ si jẹ́ ẹgba mẹdogun o le ẹdẹgbẹta; ninu eyiti idá ti OLUWA jẹ́ ọgọta o le ọkan.

Num 31

Num 31:33-48