Num 31:27 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki o si pín ikogun na si ipa meji; lãrin awọn ologun, ti o jade lọ si ogun na, ati lãrin gbogbo ijọ.

Num 31

Num 31:26-30