Num 31:24 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki ẹnyin ki o si fọ̀ aṣọ nyin ni ijọ́ keje, ẹnyin o si di mimọ́, lẹhin eyinì li ẹnyin o si wá sinu ibudó.

Num 31

Num 31:15-29