Num 31:10 Yorùbá Bibeli (YCE)

Nwọn si fi iná kun gbogbo ilu wọn ninu eyiti nwọn ngbé, ati gbogbo ibudó wọn.

Num 31

Num 31:5-12