Num 3:9 Yorùbá Bibeli (YCE)

Ki iwọ ki o si fi awọn ọmọ Lefi fun Aaroni ati fun awọn ọmọ rẹ̀: patapata li a fi wọn fun u ninu awọn ọmọ Israeli.

Num 3

Num 3:4-11